Ọna ọfun, ọna ọrun, olorin takasufe ilẹ Amẹrika, Lady gaga ṣubu yakata lori itage to ti n kọrin niluu Las Vegas. Iṣẹlẹ yii waye nigba ti Lady Gaga fẹ pe ọkan lara awọn ololufẹ rẹ, Jack pe ko goke wa.
Some results have been hidden because they may be inaccessible to you
Show inaccessible results